-
Jẹ́nẹ́sísì 35:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọmọkùnrin tí Líà bí ni Rúbẹ́nì+ tó jẹ́ àkọ́bí Jékọ́bù, lẹ́yìn náà, ó bí Síméónì, Léfì, Júdà, Ísákà àti Sébúlúnì.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 46:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Àwọn ọmọ Ísákà ni Tólà, Púfà, Íóbù àti Ṣímúrónì.+
-
-
1 Kíróníkà 7:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Àwọn ọmọ Ísákà ni Tólà, Púà, Jáṣúbù àti Ṣímúrónì,+ wọ́n jẹ́ mẹ́rin.
-