-
1 Kíróníkà 7:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Àwọn ọmọ Tólà ni Úsáì, Refáyà, Jéríélì, Jámáì, Íbísámù àti Ṣẹ́múẹ́lì, àwọn olórí agbo ilé bàbá wọn. Àwọn àtọmọdọ́mọ Tólà jẹ́ jagunjagun tó lákíkanjú, iye wọn ní ìgbà ayé Dáfídì jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́fà (22,600).
-