Nọ́ńbà 32:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+ Nọ́ńbà 33:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Àlùfáà Áárónì wá gun Òkè Hóórì lọ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, ó sì kú síbẹ̀ ní ọjọ́ kìíní, oṣù+ karùn-ún, ọdún ogójì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
13 Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì, ó sì mú kí wọ́n fi ogójì (40) ọdún+ rìn kiri nínú aginjù, títí gbogbo ìran tó ń hùwà ibi lójú Jèhófà fi pa run.+
38 Àlùfáà Áárónì wá gun Òkè Hóórì lọ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, ó sì kú síbẹ̀ ní ọjọ́ kìíní, oṣù+ karùn-ún, ọdún ogójì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.