-
1 Àwọn Ọba 9:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Sólómọ́nì tún kọ́ gbogbo àwọn ìlú tó ń kó nǹkan pa mọ́ sí, àwọn ìlú kẹ̀kẹ́ ẹṣin,+ àwọn ìlú àwọn agẹṣin àti ohunkóhun tó wu Sólómọ́nì láti kọ́ sí Jerúsálẹ́mù, sí Lẹ́bánónì àti sí gbogbo ilẹ̀ tó ń ṣàkóso lé lórí.
-