Diutarónómì 6:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí o fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ara* rẹ+ àti gbogbo okun rẹ*+ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ.