Róòmù 10:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ kí ni Ìwé Mímọ́ sọ? “Tòsí rẹ ni ọ̀rọ̀ náà wà, ní ẹnu rẹ àti ọkàn rẹ”;+ ìyẹn, “ọ̀rọ̀” ìgbàgbọ́, tí à ń wàásù.
8 Àmọ́ kí ni Ìwé Mímọ́ sọ? “Tòsí rẹ ni ọ̀rọ̀ náà wà, ní ẹnu rẹ àti ọkàn rẹ”;+ ìyẹn, “ọ̀rọ̀” ìgbàgbọ́, tí à ń wàásù.