Léfítíkù 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.
5 Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi àti àwọn ìdájọ́ mi mọ́; yóò mú kí ẹnikẹ́ni tó bá ń pa á mọ́ wà láàyè.+ Èmi ni Jèhófà.