18 Ẹ ṣọ́ra, kó má bàa sí ọkùnrin tàbí obìnrin kankan, ìdílé tàbí ẹ̀yà kan láàárín yín lónìí tí ọkàn rẹ̀ máa yí pa dà kúrò lọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wa láti lọ sin àwọn ọlọ́run àwọn orílẹ̀-èdè yẹn,+ kó má bàa sí gbòǹgbò kankan láàárín yín tó ń so èso tó ní májèlé àti iwọ.+