-
Ẹ́kísódù 7:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹni ọgọ́rin (80) ọdún ni Mósè, ẹni ọdún mẹ́tàlélọ́gọ́rin (83) sì ni Áárónì nígbà tí wọ́n bá Fáráò sọ̀rọ̀.+
-
-
Diutarónómì 34:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ẹni ọgọ́fà (120) ọdún ni Mósè nígbà tó kú.+ Ojú rẹ̀ ò di bàìbàì, agbára rẹ̀ ò sì dín kù.
-