Nọ́ńbà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́ ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ẹ má sì bẹ̀rù àwọn èèyàn ilẹ̀ náà,+ torí a máa jẹ wọ́n run.* Ààbò wọn ti kúrò lórí wọn, Jèhófà sì wà pẹ̀lú wa.+ Ẹ má bẹ̀rù wọn.” Diutarónómì 7:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 o ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù wọn.+ Rán ara rẹ létí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sí Fáráò àti gbogbo Íjíbítì,+
9 Àmọ́ ẹ má ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà, ẹ má sì bẹ̀rù àwọn èèyàn ilẹ̀ náà,+ torí a máa jẹ wọ́n run.* Ààbò wọn ti kúrò lórí wọn, Jèhófà sì wà pẹ̀lú wa.+ Ẹ má bẹ̀rù wọn.”
18 o ò gbọ́dọ̀ bẹ̀rù wọn.+ Rán ara rẹ létí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ ṣe sí Fáráò àti gbogbo Íjíbítì,+