Jóṣúà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà sọ fún wọn pé: “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà.+ Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára, torí ohun tí Jèhófà máa ṣe sí gbogbo àwọn ọ̀tá yín tí ẹ̀ ń bá jà nìyí.”+
25 Lẹ́yìn náà, Jóṣúà sọ fún wọn pé: “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà.+ Ẹ jẹ́ onígboyà àti alágbára, torí ohun tí Jèhófà máa ṣe sí gbogbo àwọn ọ̀tá yín tí ẹ̀ ń bá jà nìyí.”+