Diutarónómì 29:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Jèhófà ò ní ṣe tán láti dárí jì í.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, Jèhófà máa bínú gidigidi sí ẹni náà, ó dájú pé gbogbo ègún tí wọ́n sì kọ sínú ìwé yìí máa wá sórí rẹ̀,+ ó sì dájú pé Jèhófà máa pa orúkọ rẹ̀ rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run.
20 Jèhófà ò ní ṣe tán láti dárí jì í.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, Jèhófà máa bínú gidigidi sí ẹni náà, ó dájú pé gbogbo ègún tí wọ́n sì kọ sínú ìwé yìí máa wá sórí rẹ̀,+ ó sì dájú pé Jèhófà máa pa orúkọ rẹ̀ rẹ́ kúrò lábẹ́ ọ̀run.