Nehemáyà 9:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nítorí èyí, o fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn,+ wọ́n sì ń kó wàhálà bá wọn.+ Àmọ́, wọ́n á ké pè ọ́ ní àkókò wàhálà wọn, ìwọ náà á sì gbọ́ láti ọ̀run; nítorí àánú ńlá rẹ, wàá fún wọn ní olùgbàlà láti gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn.+
27 Nítorí èyí, o fi wọ́n lé ọwọ́ àwọn ọ̀tá wọn,+ wọ́n sì ń kó wàhálà bá wọn.+ Àmọ́, wọ́n á ké pè ọ́ ní àkókò wàhálà wọn, ìwọ náà á sì gbọ́ láti ọ̀run; nítorí àánú ńlá rẹ, wàá fún wọn ní olùgbàlà láti gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn.+