Jóṣúà 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+ Jóṣúà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+
6 Jẹ́ onígboyà àti alágbára,+ torí ìwọ lo máa mú kí àwọn èèyàn yìí jogún ilẹ̀ tí mo búra fún àwọn baba ńlá wọn pé màá fún wọn.+
9 Ṣebí mo ti pàṣẹ fún ọ? Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀rù bà ọ́, má sì jáyà, torí Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ.”+