1 Kíróníkà 29:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà, tìrẹ ni títóbi+ àti agbára ńlá+ àti ẹwà àti ògo àti ọlá ńlá,*+ nítorí gbogbo ohun tó wà ní ọ̀run àti ní ayé jẹ́ tìrẹ.+ Jèhófà, tìrẹ ni ìjọba.+ Ìwọ ni Ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe olórí lórí ohun gbogbo. Sáàmù 145:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà tóbi, òun sì ni ìyìn yẹ jù lọ,+Àwámáridìí ni títóbi rẹ̀.*+
11 Jèhófà, tìrẹ ni títóbi+ àti agbára ńlá+ àti ẹwà àti ògo àti ọlá ńlá,*+ nítorí gbogbo ohun tó wà ní ọ̀run àti ní ayé jẹ́ tìrẹ.+ Jèhófà, tìrẹ ni ìjọba.+ Ìwọ ni Ẹni tó fi ara rẹ̀ ṣe olórí lórí ohun gbogbo.