Sáàmù 33:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó nífẹ̀ẹ́ òdodo àti ìdájọ́ òdodo.+ Ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ kún inú ayé.+