Sáàmù 78:71 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 71 Kúrò ní ibi tó ti ń tọ́jú àwọn abo àgùntàn tó ń fọ́mọ lọ́mú;Ó fi í ṣe olùṣọ́ àgùntàn lórí Jékọ́bù, àwọn èèyàn rẹ̀+Àti lórí Ísírẹ́lì, ogún rẹ̀.+
71 Kúrò ní ibi tó ti ń tọ́jú àwọn abo àgùntàn tó ń fọ́mọ lọ́mú;Ó fi í ṣe olùṣọ́ àgùntàn lórí Jékọ́bù, àwọn èèyàn rẹ̀+Àti lórí Ísírẹ́lì, ogún rẹ̀.+