1 Kíróníkà 2:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ségúbù bí Jáírì,+ ẹni tó ní ìlú mẹ́tàlélógún (23) ní ilẹ̀ Gílíádì.+