-
Diutarónómì 1:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ẹ sì rí i bí Jèhófà Ọlọ́run yín ṣe gbé yín nínú aginjù, bí bàbá ṣe ń gbé ọmọ rẹ̀, tó sì ń gbé yín kiri gbogbo ibi tí ẹ lọ títí ẹ fi dé ibí yìí.’
-