Àìsáyà 43:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Èmi ni Ẹni tó kéde, tó gbani là, tó sì mú kó di mímọ̀,Nígbà tí kò sí ọlọ́run àjèjì kankan láàárín yín.+ Torí náà, ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Jèhófà wí, “èmi sì ni Ọlọ́run.+
12 “Èmi ni Ẹni tó kéde, tó gbani là, tó sì mú kó di mímọ̀,Nígbà tí kò sí ọlọ́run àjèjì kankan láàárín yín.+ Torí náà, ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Jèhófà wí, “èmi sì ni Ọlọ́run.+