Jóṣúà 13:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò lé+ àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì kúrò,* torí àwọn Géṣúrì àti Máákátì ṣì wà láàárín Ísírẹ́lì títí di òní yìí.
13 Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò lé+ àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì kúrò,* torí àwọn Géṣúrì àti Máákátì ṣì wà láàárín Ísírẹ́lì títí di òní yìí.