Sáàmù 96:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Gbogbo ọlọ́run àwọn èèyàn jẹ́ ọlọ́run asán,+Àmọ́ Jèhófà ló dá ọ̀run.+ 1 Kọ́ríńtì 10:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ẹ ò lè máa mu nínú ife Jèhófà* àti ife àwọn ẹ̀mí èṣù; ẹ ò lè máa jẹun lórí “tábìlì Jèhófà”*+ àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù. 22 Àbí ‘ṣé a fẹ́ máa mú Jèhófà* jowú ni’?+ A ò lágbára jù ú lọ, àbí a ní?
21 Ẹ ò lè máa mu nínú ife Jèhófà* àti ife àwọn ẹ̀mí èṣù; ẹ ò lè máa jẹun lórí “tábìlì Jèhófà”*+ àti tábìlì àwọn ẹ̀mí èṣù. 22 Àbí ‘ṣé a fẹ́ máa mú Jèhófà* jowú ni’?+ A ò lágbára jù ú lọ, àbí a ní?