Léfítíkù 26:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Èmi yóò rán àwọn ẹran inú igbó sáàárín yín,+ wọ́n á pa yín lọ́mọ jẹ,+ wọ́n á pa àwọn ẹran ọ̀sìn yín run, wọ́n á dín iye yín kù, àwọn ọ̀nà yín yóò sì dá páropáro.+
22 Èmi yóò rán àwọn ẹran inú igbó sáàárín yín,+ wọ́n á pa yín lọ́mọ jẹ,+ wọ́n á pa àwọn ẹran ọ̀sìn yín run, wọ́n á dín iye yín kù, àwọn ọ̀nà yín yóò sì dá páropáro.+