Hósíà 14:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ta ni ó gbọ́n? Kí ó lóye nǹkan wọ̀nyí. Ta ni ó lóye? Kí ó mọ̀ wọ́n. Nítorí àwọn ọ̀nà Jèhófà tọ́,+Àwọn olódodo yóò sì máa rìn nínú wọn;Àmọ́, àwọn tó ń dẹ́ṣẹ̀ yóò kọsẹ̀ nínú wọn.
9 Ta ni ó gbọ́n? Kí ó lóye nǹkan wọ̀nyí. Ta ni ó lóye? Kí ó mọ̀ wọ́n. Nítorí àwọn ọ̀nà Jèhófà tọ́,+Àwọn olódodo yóò sì máa rìn nínú wọn;Àmọ́, àwọn tó ń dẹ́ṣẹ̀ yóò kọsẹ̀ nínú wọn.