Náhúmù 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà kì í tètè bínú,+ agbára rẹ̀ sì pọ̀,+Àmọ́, Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tí ìyà bá tọ́ sí.+ Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú ẹ̀fúùfù àti ìjì líle,Àwọsánmà sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.+
3 Jèhófà kì í tètè bínú,+ agbára rẹ̀ sì pọ̀,+Àmọ́, Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tí ìyà bá tọ́ sí.+ Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú ẹ̀fúùfù àti ìjì líle,Àwọsánmà sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.+