-
2 Àwọn Ọba 9:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kí o pa àwọn ará ilé Áhábù olúwa rẹ, màá sì gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì àti ti gbogbo ìránṣẹ́ Jèhófà tí Jésíbẹ́lì pa.+
-