Jẹ́nẹ́sísì 49:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ìwọ̀nyí ni ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì. Ohun tí bàbá wọn sì sọ fún wọn nìyẹn nígbà tó ń súre fún wọn. Ó súre+ fún kálukú bó ṣe tọ́ sí i.
28 Ìwọ̀nyí ni ẹ̀yà méjìlá (12) Ísírẹ́lì. Ohun tí bàbá wọn sì sọ fún wọn nìyẹn nígbà tó ń súre fún wọn. Ó súre+ fún kálukú bó ṣe tọ́ sí i.