-
Ẹ́kísódù 20:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Torí náà, wọ́n sọ fún Mósè pé: “Ìwọ ni kí o máa bá wa sọ̀rọ̀, a ó sì fetí sílẹ̀. Má ṣe jẹ́ kí Ọlọ́run bá wa sọ̀rọ̀ ká má bàa kú.”+
-