-
Ẹ́kísódù 18:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Mósè yan àwọn ọkùnrin tó kúnjú ìwọ̀n nínú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì fi wọ́n ṣe olórí àwọn èèyàn náà, ó fi wọ́n ṣe olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún, olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún, olórí àràádọ́ta àti olórí àwọn mẹ́wàá-mẹ́wàá.
-
-
Ẹ́kísódù 19:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Mósè wá pe àwọn àgbààgbà láàárín àwọn èèyàn náà, ó sì sọ fún wọn nípa gbogbo ọ̀rọ̀ yìí tí Jèhófà pa láṣẹ fún un.+
-