Ẹ́kísódù 28:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo. Léfítíkù 8:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mósè wá mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ sún mọ́ tòsí, ó sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ Léfítíkù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ó wá wọ aṣọ ìgbàyà+ fún un, ó sì fi Úrímù àti Túmímù+ sí aṣọ ìgbàyà náà.
30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.