Jẹ́nẹ́sísì 49:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Bẹ́ńjámínì+ yóò máa fani ya bí ìkookò.+ Ní àárọ̀, yóò jẹ ẹran tó pa. Ní ìrọ̀lẹ́, yóò pín ẹrù ogun.”+
27 “Bẹ́ńjámínì+ yóò máa fani ya bí ìkookò.+ Ní àárọ̀, yóò jẹ ẹran tó pa. Ní ìrọ̀lẹ́, yóò pín ẹrù ogun.”+