-
Ẹ́kísódù 3:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà tí Jèhófà rí i pé ó lọ wò ó, Ọlọ́run pè é látinú igi ẹlẹ́gùn-ún náà pé: “Mósè! Mósè!” Ó dáhùn pé: “Èmi nìyí.”
-
-
Ìṣe 7:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 “Lẹ́yìn ogójì (40) ọdún, áńgẹ́lì kan fara hàn án ní aginjù Òkè Sínáì nínú ọwọ́ iná tó ń jó lára igi ẹlẹ́gùn-ún.+
-