-
Jẹ́nẹ́sísì 48:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àmọ́ bàbá rẹ̀ ò gbà, ó sì sọ pé: “Mo mọ̀, ọmọ mi, mo mọ̀. Òun náà á di èèyàn púpọ̀, yóò sì di ẹni ńlá. Àmọ́, àbúrò rẹ̀ máa jù ú lọ,+ àwọn ọmọ* rẹ̀ yóò sì pọ̀ bí àwọn orílẹ̀-èdè.”+ 20 Ó sì súre fún wọn ní ọjọ́+ yẹn, ó ní:
“Kí Ísírẹ́lì máa fi orúkọ rẹ súre pé,
‘Kí Ọlọ́run mú kí o dà bí Éfúrémù àti Mánásè.’”
Ó wá ń fi Éfúrémù ṣáájú Mánásè.
-