ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 13:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Láàárín àkókò yìí, ọkùnrin ará Sórà+ kan wà, ó wá látinú ìdílé àwọn ọmọ Dánì,+ Mánóà+ ni orúkọ rẹ̀. Ìyàwó rẹ̀ yàgàn, kò sì bímọ kankan.+

  • Àwọn Onídàájọ́ 13:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Lẹ́yìn náà, obìnrin náà bí ọmọkùnrin kan, ó sì sọ ọ́ ní Sámúsìn;+ bí ọmọ náà ṣe ń dàgbà, Jèhófà ń bù kún un.

  • Àwọn Onídàájọ́ 15:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í pa wọ́n níkọ̀ọ̀kan,* ó pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ, lẹ́yìn náà, ó lọ ń gbé inú ihò* kan ní àpáta Étámì.

  • Àwọn Onídàájọ́ 15:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ogún (20) ọdún+ ló fi jẹ́ onídàájọ́ ní Ísírẹ́lì nígbà ayé àwọn Filísínì.

  • Àwọn Onídàájọ́ 16:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Sámúsìn kígbe pé: “Jẹ́ kí n* kú pẹ̀lú àwọn Filísínì.” Ó wá fi gbogbo agbára rẹ̀ tì í, ilé náà sì wó lu àwọn alákòóso náà àti gbogbo àwọn èèyàn tó wà nínú rẹ̀.+ Àwọn tó pa nígbà tó kú pọ̀ ju àwọn tó pa nígbà tó wà láàyè lọ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́