Àìsáyà 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:* ‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn.
2 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Aṣẹ̀dá rẹ àti Ẹni tó dá ọ,+Ẹni tó ràn ọ́ lọ́wọ́ látinú oyún:* ‘Má bẹ̀rù, Jékọ́bù ìránṣẹ́ mi+Àti ìwọ, Jéṣúrúnì,*+ ẹni tí mo yàn.