Àìsáyà 40:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+
11 Ó máa bójú tó* agbo ẹran rẹ̀ bíi ti olùṣọ́ àgùntàn.+ Ó máa fi apá rẹ̀ kó àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn jọ,Ó sì máa gbé wọn sí àyà rẹ̀. Ó máa rọra da àwọn tó ń fọ́mọ lọ́mú.+