Àwọn Onídàájọ́ 18:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Bákan náà, wọ́n sọ ìlú náà ní Dánì,+ ìyẹn Dánì orúkọ bàbá wọn, ẹni tí wọ́n bí fún Ísírẹ́lì.+ Àmọ́ Láíṣì ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.+
29 Bákan náà, wọ́n sọ ìlú náà ní Dánì,+ ìyẹn Dánì orúkọ bàbá wọn, ẹni tí wọ́n bí fún Ísírẹ́lì.+ Àmọ́ Láíṣì ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.+