Júùdù 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kódà nígbà tí Máíkẹ́lì+ olú áńgẹ́lì+ ń bá Èṣù fa ọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń jiyàn nípa òkú Mósè,+ kò jẹ́ dá a lẹ́jọ́, kò sì sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí i,+ àmọ́ ó sọ fún un pé: “Kí Jèhófà* bá ọ wí.”+
9 Kódà nígbà tí Máíkẹ́lì+ olú áńgẹ́lì+ ń bá Èṣù fa ọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń jiyàn nípa òkú Mósè,+ kò jẹ́ dá a lẹ́jọ́, kò sì sọ̀rọ̀ tí kò dáa sí i,+ àmọ́ ó sọ fún un pé: “Kí Jèhófà* bá ọ wí.”+