Jóṣúà 1:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Lẹ́yìn ikú Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà*+ ọmọ Núnì, ìránṣẹ́+ Mósè pé: 2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
1 Lẹ́yìn ikú Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà, Jèhófà sọ fún Jóṣúà*+ ọmọ Núnì, ìránṣẹ́+ Mósè pé: 2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+