-
Diutarónómì 3:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 A wá gba gbogbo ìlú rẹ̀. Kò sí ìlú tí a kò gbà lọ́wọ́ wọn, ọgọ́ta (60) ìlú ní gbogbo agbègbè Ágóbù, ilẹ̀ ọba Ógù ní Báṣánì.+
-