-
Ẹ́kísódù 23:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 “Ọjọ́ mẹ́fà ni kí o máa fi ṣe iṣẹ́ rẹ; àmọ́ ní ọjọ́ keje, kí o ṣíwọ́ iṣẹ́, kí akọ màlúù rẹ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ lè sinmi, kí ara sì lè tu ọmọ ẹrúbìnrin rẹ àti àjèjì.+
-