Òwe 29:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ìbẹ̀rù* èèyàn jẹ́* ìdẹkùn,+Àmọ́ ẹni tó bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà yóò rí ààbò.+