ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 21:33-35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+ 34 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Má bẹ̀rù rẹ̀,+ torí màá fi òun àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ àti ilẹ̀ rẹ̀ lé ọ lọ́wọ́,+ ohun tí o ṣe sí Síhónì, ọba àwọn Ámórì tó gbé ní Hẹ́ṣíbónì+ gẹ́lẹ́ ni wàá ṣe sí i.” 35 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í bá òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀ jà, títí ìkankan nínú àwọn èèyàn rẹ̀ ò fi ṣẹ́ kù,+ wọ́n sì gba ilẹ̀+ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́