-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Diutarónómì 28:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 “Jèhófà máa fi eéwo ilẹ̀ Íjíbítì kọ lù yín, pẹ̀lú jẹ̀díjẹ̀dí, ifo àti àwúfọ́, èyí tí kò ní ṣeé wò sàn.
-