Ẹ́kísódù 23:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Màá mú kí àwọn èèyàn rẹ̀wẹ̀sì* kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ ìrẹ̀wẹ̀sì náà yóò sì lé àwọn Hífì, àwọn ọmọ Kénáánì àti àwọn ọmọ Hétì kúrò níwájú yín.+ Jóṣúà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jóṣúà sì sọ pé: “Báyìí lẹ ṣe máa mọ̀ pé Ọlọ́run alààyè kan wà láàárín yín,+ ó sì dájú pé ó máa lé àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Hífì, àwọn Pérísì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Ámórì àti àwọn ará Jébúsì kúrò níwájú yín.+
28 Màá mú kí àwọn èèyàn rẹ̀wẹ̀sì* kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn,+ ìrẹ̀wẹ̀sì náà yóò sì lé àwọn Hífì, àwọn ọmọ Kénáánì àti àwọn ọmọ Hétì kúrò níwájú yín.+
10 Jóṣúà sì sọ pé: “Báyìí lẹ ṣe máa mọ̀ pé Ọlọ́run alààyè kan wà láàárín yín,+ ó sì dájú pé ó máa lé àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Hétì, àwọn Hífì, àwọn Pérísì, àwọn Gẹ́gáṣì, àwọn Ámórì àti àwọn ará Jébúsì kúrò níwájú yín.+