Òwe 3:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọmọ mi, má gbàgbé ẹ̀kọ́* mi,Sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́, 2 Nítorí wọ́n á fi ọ̀pọ̀ ọjọ́Àti ẹ̀mí gígùn pẹ̀lú àlàáfíà kún un fún ọ.+
3 Ọmọ mi, má gbàgbé ẹ̀kọ́* mi,Sì jẹ́ kí ọkàn rẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́, 2 Nítorí wọ́n á fi ọ̀pọ̀ ọjọ́Àti ẹ̀mí gígùn pẹ̀lú àlàáfíà kún un fún ọ.+