Hósíà 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ibi ìjẹko wọn tẹ́ wọn lọ́rùn,+Wọ́n yó, wọ́n sì ń gbéra ga. Torí náà, wọ́n gbàgbé mi.+