Nọ́ńbà 20:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ni Mósè bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó sì fi ọ̀pá rẹ̀ lu àpáta náà lẹ́ẹ̀mejì, omi púpọ̀ wá ń tú jáde, àpéjọ náà àtàwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í mu ún.+
11 Ni Mósè bá gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó sì fi ọ̀pá rẹ̀ lu àpáta náà lẹ́ẹ̀mejì, omi púpọ̀ wá ń tú jáde, àpéjọ náà àtàwọn ẹran ọ̀sìn wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í mu ún.+