Ẹ́kísódù 16:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ mánà fún ogójì (40) ọdún,+ títí wọ́n fi dé ilẹ̀ kan tí àwọn èèyàn ń gbé.+ Wọ́n jẹ mánà títí wọ́n fi dé ààlà ilẹ̀ Kénáánì.+
35 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ mánà fún ogójì (40) ọdún,+ títí wọ́n fi dé ilẹ̀ kan tí àwọn èèyàn ń gbé.+ Wọ́n jẹ mánà títí wọ́n fi dé ààlà ilẹ̀ Kénáánì.+