Ẹ́kísódù 32:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní báyìí, fi mí sílẹ̀, màá fi ìbínú mi tó ń jó bí iná pa wọ́n run, kí o sì jẹ́ kí n sọ ìwọ di orílẹ̀-èdè ńlá dípò wọn.”+
10 Ní báyìí, fi mí sílẹ̀, màá fi ìbínú mi tó ń jó bí iná pa wọ́n run, kí o sì jẹ́ kí n sọ ìwọ di orílẹ̀-èdè ńlá dípò wọn.”+